New Patient Exam & X-rays $19 ➞

nondiscrimination akiyesi

AKIYESI: Bi o ba nsọ èdè Yorùbú ọfé ni iranlọwọ lori èdè wa fun yin o. Ẹ pe ẹrọ-ibanisọrọ yi 1-800-220-6277.

Iyasoto jẹ Lodi si Ofin

Comfort Dental:

Ba ilana ijọba apapọ lori ofin etọ ara ilu ati pe a ko gbọdọ ṣe ojuṣaaju nipa ẹya, àwo, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin.

Comfort Dental:

Wọn ko gbọdọ yọ awọn eniyan silẹ tabi wuwasi wọn yatọ l’atari eyà, àwo, abinibi, ọọ-ori, tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin.

Comfort Dental:

Npese-ohun-elo ọfọ ati iranlọwọ fun awọn alaabọ-ara lati le sọrọ ni ọna ti o munadoko, bii:

Comfort Dental:

A npese ogbufo l’ọfẹ fun awọn ti èdè abinibi wọn kìí ṣe èdè Gẹẹsi

Bi o ba nfẹ awọn anfani wọnyi, kansi your local office.

Ti o ba gbagbọ pe:

Comfort Dental

Ti kuna lati pese awọn iṣẹ wọnyi tabi iyasoto ni ọna miiran lori ipilẹ ti ẹya, awọ, orisun orilẹ-ede, ọjọ-ori, alaabo, tabi ibalopọ, o le fi ẹsun kan pẹlu:

Ẹ le fi iwe ifi ẹhonu han ni ojukoroju tabi nipa fifi ranṣẹ ni apo-iwe si adirẹsi wa, faksi, tabi ẹrọ-ayelujara. Bi ẹ ba nilo iranlọwọ lati kọ iwe ifi-ẹhonu han, your local office, Compliance Officer wa ni sẹpẹ fun yin.

Ẹ tun le pe kotẹmilọrun l’atari etọara-ilu pẹlu U.S Department of Health and Human Services, Office for Civil Rights, Office fun Civil Rights Complain Portal, wa ni https://ocrportal.hhs.gov/ocr/portal/lobby.jsf tabi nipa fifi iwe-sọwọ tabi lori ẹrọ-ibanisọrọ ni:

200 Independence Avenue, SW Room 509F, HHH Building Washington, D.C. 20201 1-800-368-1019, 800-537-7697 (TDD) Ẹ le ri fọọmu fun ẹhonu ni http://www.hhs.gov/ocr/office/file/index.html