AKIYESI: Bi o ba nsọ èdè Yorùbú ọfé ni iranlọwọ lori èdè wa fun yin o. Ẹ pe ẹrọ-ibanisọrọ yi 1-800-220-6277. Iyasoto jẹ Lodi si Ofin Colfax and Havana Dental Partners, PLLP: Ba ilana ijọba apapọ lori ofin etọ ara ilu ati pe a ko gbọdọ ṣe ojuṣaaju nipa ẹya, àwo, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin. Colfax and Havana Dental Partners, PLLP: Wọn ko gbọdọ yọ awọn eniyan silẹ tabi wuwasi wọn yatọ l’atari eyà, àwo, abinibi, ọọ-ori, tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin. Colfax and Havana Dental Partners, PLLP: Npese-ohun-elo ọfọ ati iranlọwọ fun awọn alaabọ-ara lati le sọrọ ni ọna ti o munadoko, bii: o Akọṣẹmọṣẹ ogbufọ odi o Kikọo ọrọ jade ni ọna miran (kikọ ọrọ ni titobi, agbohunsilẹ, awọn ohunelo igbalode fun ẹrọ ayelujara ati awọn ọna miran.) Colfax and Havana Dental Partners, PLLP: A npese ogbufo l’ọfẹ fun awọn ti èdè abinibi wọn kìí ṣe èdè Gẹẹsi o Akọṣẹmọṣẹ ogbufọ o Kikọ ọrọ ni awọn èdè miran Bi o ba nfẹ awọn anfani wọnyi, kansi Dr. Jeffrey Crane. Bi ẹ ba nigbagbo wipe Colfax and Havana Dental Partners, PLLP ti kuna lati ṣeto awọn iranlọwọ wọnyi tabi ṣe ojuṣaaaju ni awọn ọna miran bi ẹlẹyamẹya, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa, tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin, le fi iwe kotẹmi-lọrun/iwe ifẹhonu han si: Dr. Jeffrey Crane, Compliance Officer 10401 E Colfax Ave
Aurora, CO 80010 Foonu: 303-344-2273 Faksi: 303-344-2286 jcrane@comfortdental.biz Ẹ le fi iwe ifi ẹhonu han ni ojukoroju tabi nipa fifi ranṣẹ ni apo-iwe si adirẹsi wa, faksi, tabi ẹrọ-ayelujara. Bi ẹ ba nilo iranlọwọ lati kọ iwe ifi-ẹhonu han, Dr. Jeffrey Crane, Compliance Officer wa ni sẹpẹ fun yin. Ẹ tun le pe kotẹmilọrun l’atari etọara-ilu pẹlu U.S Department of Health and Human Services, Office for Civil Rights, Office fun Civil Rights Complain Portal, wa ni https://ocrportal.hhs.gov/ocr/portal/lobby.jsf tabi nipa fifi iwe-sọwọ tabi lori ẹrọ-ibanisọrọ ni: 200 Independence Avenue, SW Room 509F, HHH Building Washington, D.C. 20201 1-800-368-1019, 800-537-7697 (TDD) Ẹ le ri fọọmu fun ẹhonu ni http://www.hhs.gov/ocr/office/file/index.html